YouVersion Logo
Search Icon

ÀWỌN ADÁJỌ́ 16:30

ÀWỌN ADÁJỌ́ 16:30 YCE

Ó wí pé, “Jẹ́ kí èmi náà kú pẹlu àwọn ará Filistia.” Ó bá bẹ̀rẹ̀ pẹlu gbogbo agbára rẹ̀. Ilé náà sì wó lu gbogbo àwọn ọba Filistini ati gbogbo àwọn eniyan tí wọ́n wà ninu rẹ̀. Nítorí náà, iye eniyan tí ó pa nígbà tí òun náà yóo fi kú, ju àwọn tí ó pa nígbà tí ó wà láàyè lọ.

Video for ÀWỌN ADÁJỌ́ 16:30

Free Reading Plans and Devotionals related to ÀWỌN ADÁJỌ́ 16:30