YouVersion Logo
Search Icon

ÀWỌN ADÁJỌ́ 17:6

ÀWỌN ADÁJỌ́ 17:6 YCE

Kò sí ọba ní ilẹ̀ Israẹli ní gbogbo àkókò náà, nítorí náà ohun tí ó bá tọ́ lójú olukuluku ni olukuluku ń ṣe.