YouVersion Logo
Search Icon

ÀWỌN ADÁJỌ́ 6:11

ÀWỌN ADÁJỌ́ 6:11 YCE

Angẹli OLUWA kan wá, ó jókòó lábẹ́ igi Oaku tí ó wà ní Ofira, igi Oaku yìí jẹ́ ti Joaṣi, ará Abieseri. Bí Gideoni ọmọ Joaṣi, ti ń pa ọkà ní ibi tí wọ́n ti ń pọn ọtí, tí ó ń fi í pamọ́ fún àwọn ará Midiani

Free Reading Plans and Devotionals related to ÀWỌN ADÁJỌ́ 6:11