ORIN SOLOMONI 8:6
ORIN SOLOMONI 8:6 YCE
Gbé mi lé oókan àyà rẹ bí èdìdì ìfẹ́, bí èdìdì, ní apá rẹ; nítorí ìfẹ́ lágbára bí ikú. Owú jíjẹ burú, àfi bí isà òkú. A máa jó bí iná, bí ọwọ́ iná tí ó lágbára.