YouVersion Logo
Search Icon

Mak 12:41-42

Mak 12:41-42 YBCV

Jesu si joko kọjusi apoti iṣura, o si nwò bi ijọ enia ti nsọ owo sinu apoti iṣura: ọ̀pọ awọn ọlọrọ̀ si sọ pipọ si i. Talakà opó kan si wá, o sọ owo idẹ wẹ́wẹ meji ti iṣe idameji owo-bàba kan sinu rẹ̀.

Free Reading Plans and Devotionals related to Mak 12:41-42