Ifi 22:20-21
Ifi 22:20-21 YBCV
Ẹniti o jẹri nkan wọnyi wipe, Nitõtọ emi mbọ̀ kánkán. Amin. Mã bọ̀, Jesu Oluwa. Ore-ọfẹ Jesu Oluwa ki o wà pẹlu gbogbo awọn enia mimọ́. Amin.