YouVersion Logo
Search Icon

1 Samuẹli 1:15

1 Samuẹli 1:15 YCB

Hana dá a lóhùn pé, “Bẹ́ẹ̀ kọ́, OLúWA mi,” “Èmi ni obìnrin oníròbìnújẹ́. Èmi kò mu ọtí wáìnì tàbí ọtí líle; Èmi ń tú ọkàn mi jáde sí OLúWA ni.

Free Reading Plans and Devotionals related to 1 Samuẹli 1:15