1 Samuẹli 12:20
1 Samuẹli 12:20 YCB
Samuẹli sì dá wọn lóhùn pé, “Ẹ má bẹ̀rù, ẹ ti ṣe gbogbo búburú yìí; síbẹ̀ ẹ má ṣe yípadà kúrò lọ́dọ̀ OLúWA, ṣùgbọ́n ẹ fi gbogbo àyà yín sin OLúWA.