YouVersion Logo
Search Icon

Ìṣe àwọn Aposteli 2:46-47

Ìṣe àwọn Aposteli 2:46-47 YCB

Wọ́n fi ọkàn kan dúró lójoojúmọ́ nínú tẹmpili. Wọ́n ń bu àkàrà ní ilé wọn, wọn ń fi inú dídùn àti ọkàn òtítọ́ jẹ oúnjẹ wọn. Wọ́n yín Ọlọ́run, wọn sì rí ojúrere lọ́dọ̀ ènìyàn gbogbo, Olúwa sí ń yàn kún wọn lójoojúmọ́, àwọn tí à ń gbàlà.

Video for Ìṣe àwọn Aposteli 2:46-47