YouVersion Logo
Search Icon

Efesu 5:15-16

Efesu 5:15-16 YCB

Nítorí náà ẹ kíyèsi láti máa rìn ní ìwà pípé, kì í ṣé bí àwọn òmùgọ̀, ṣùgbọ́n bí àwọn ọlọ́gbọ́n; Ẹ máa ra ìgbà padà, nítorí búburú ní àwọn ọjọ́.

Video for Efesu 5:15-16