YouVersion Logo
Search Icon

Eksodu 8:1

Eksodu 8:1 YCB

Nígbà náà ni OLúWA sọ fún Mose pé, “Padà tọ Farao lọ kí ó sì sọ fún un pé, ‘Èyí ni OLúWA wí: Jẹ́ kí àwọn ènìyàn mi kí ó lọ, kí wọn ó bá à lè sìn mi.