Isaiah 24:23
Isaiah 24:23 YCB
A ó rẹ òṣùpá sílẹ̀, ojú yóò sì ti oòrùn; nítorí OLúWA àwọn ọmọ-ogun yóò jẹ ọba ní orí òkè Sioni àti ní Jerusalẹmu, àti níwájú àwọn àgbàgbà rẹ ní ògo.