YouVersion Logo
Search Icon

Onidajọ 6:11

Onidajọ 6:11 YCB

Ní ọjọ́ kan angẹli OLúWA wá, ó sì jókòó ní abẹ́ igi óákù ofira èyí ti ṣe ti Joaṣi ará Abieseri, níbi tí Gideoni ọmọ rẹ̀ ti ń lu ọkà jéró, níbi ìpọntí wáìnì láti fi pamọ́ kúrò níwájú àwọn ará Midiani.

Video for Onidajọ 6:11