YouVersion Logo
Search Icon

Onidajọ 6:14

Onidajọ 6:14 YCB

OLúWA sì yípadà sí i, ó sì wí fún un pé, “Lọ nínú agbára tí o ní yìí, kí o sì gba àwọn ará Israẹli sílẹ̀ kúrò lọ́wọ́ àwọn ará Midiani. Èmi ni ó ń rán ọ lọ.”

Video for Onidajọ 6:14