Saamu 11:4
Saamu 11:4 YCB
OLúWA ń bẹ nínú tẹmpili mímọ́ rẹ̀; OLúWA ń bẹ lórí ìtẹ́ rẹ̀ ní ọ̀run. Ó ń wo àwọn ọmọ ènìyàn; ojú rẹ̀ ń yẹ̀ wọ́n wò.