1
Luk 23:34
Bibeli Mimọ
Jesu si wipe, Baba, darijì wọn; nitoriti nwọn kò mọ̀ ohun ti nwọn nṣe. Nwọn si pín aṣọ rẹ̀ lãrin ara wọn, nwọn di ìbo rẹ̀.
Compara
Explorar Luk 23:34
2
Luk 23:43
Jesu si wi fun u pe, Lõtọ ni mo wi fun ọ, Loni ni iwọ o wà pẹlu mi ni Paradise.
Explorar Luk 23:43
3
Luk 23:42
O si wipe, Jesu, ranti mi nigbati iwọ ba de ijọba rẹ.
Explorar Luk 23:42
4
Luk 23:46
Nigbati Jesu si kigbe li ohùn rara, o ni, Baba, li ọwọ́ rẹ ni mo fi ẹmí mi le: nigbati o si wi eyi tan, o jọwọ ẹmí rẹ̀ lọwọ.
Explorar Luk 23:46
5
Luk 23:33
Nigbati nwọn si de ibi ti a npè ni Agbari, nibẹ̀ ni nwọn gbé kàn a mọ agbelebu, ati awọn arufin na, ọkan li ọwọ́ ọtún, ati ọkan li ọwọ́ òsi.
Explorar Luk 23:33
6
Luk 23:44-45
O si to ìwọn wakati kẹfa ọjọ, òkunkun si ṣú bò gbogbo ilẹ titi o fi di wakati kẹsan ọjọ. Õrùn si ṣú õkun, aṣọ ikele ti tẹmpili si ya li agbedemeji.
Explorar Luk 23:44-45
7
Luk 23:47
Nigbati balogun ọrún ri ohun ti o ṣe, o yìn Ọlọrun logo, wipe, Dajudaju olododo li ọkunrin yi.
Explorar Luk 23:47
Inici
La Bíblia
Plans
Vídeos