Gẹnẹsisi 8:20

Gẹnẹsisi 8:20 YCB

Noa sì mọ pẹpẹ fún OLúWA, ó sì mú lára àwọn ẹran tí ó mọ́ àti ẹyẹ tí ó mọ́, ó sì fi rú ẹbọ sísun lórí pẹpẹ.