1
Ìṣe àwọn Aposteli 7:59-60
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Bí wọ́n ti ń sọ Stefanu ní òkúta, ó sì ké pe Olúwa wí pé, “Jesu Olúwa, gba ẹ̀mí mi.” Nígbà náà ni ó wólẹ̀ lórí eékún rẹ̀, ó kígbe sókè pé, “Olúwa, má ṣe ka ẹ̀ṣẹ̀ yìí sí wọn ní ọrùn.” Nígbà ti ó sì wí èyí tán, ó sùn lọ.
Համեմատել
Ուսումնասիրեք Ìṣe àwọn Aposteli 7:59-60
2
Ìṣe àwọn Aposteli 7:49
“ ‘Ọ̀run ni ìtẹ́ mi, ayé ni àpótí ìtìsẹ̀ mi. Irú ilé kín ní ẹ̀yin yóò kọ́ fún mi? ni Olúwa wí. Tàbí níbo ni yóò jẹ́ ibi ìsinmi mi?
Ուսումնասիրեք Ìṣe àwọn Aposteli 7:49
3
Ìṣe àwọn Aposteli 7:57-58
Nígbà náà ni wọn kígbe ní ohùn rara, wọn sí di etí wọ́n, gbogbo wọn sì sáré sí i, wọ́n sì rọ́ lù ú, wọ́n sì wọ́ ọ sẹ́yìn òde ìlú, wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sísọ ọ́ ní òkúta; àwọn ẹlẹ́rìí sì fi aṣọ wọn lélẹ̀ lẹ́sẹ̀ ọmọkùnrin kan tí a ń pè ní Saulu.
Ուսումնասիրեք Ìṣe àwọn Aposteli 7:57-58
Գլխավոր
Աստվածաշունչ
Ծրագրեր
Տեսանյութեր