1
JẸNẸSISI 5:24
Yoruba Bible
Enọku wà ní ìrẹ́pọ̀ pẹlu Ọlọrun, nígbà tí ó yá, wọn kò rí i mọ́ nítorí pé Ọlọrun mú un lọ.
比較
JẸNẸSISI 5:24で検索
2
JẸNẸSISI 5:22
Lẹ́yìn tí ó bí Metusela, ó wà ní ìrẹ́pọ̀ pẹlu Ọlọrun fún ọọdunrun (300) ọdún, ó sì bí àwọn ọmọ mìíràn lọkunrin ati lobinrin.
JẸNẸSISI 5:22で検索
3
JẸNẸSISI 5:1
Àkọsílẹ̀ ìran Adamu nìyí: Nígbà tí Ọlọrun dá eniyan, ó dá wọn ní àwòrán ara rẹ̀.
JẸNẸSISI 5:1で検索
4
JẸNẸSISI 5:2
Takọ-tabo ni ó dá wọn, ó súre fún wọn, ó sì sọ wọ́n ní eniyan.
JẸNẸSISI 5:2で検索
ホーム
聖書
読書プラン
ビデオ