1
I. Tim 6:12
Bibeli Mimọ
Mã jà ìja rere ti igbagbọ́, di ìye ainipẹkun mu ninu eyiti a gbé pè ọ si, ti iwọ si ṣe ijẹwo rere niwaju ẹlẹri pupọ̀.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí I. Tim 6:12
2
I. Tim 6:10
Nitori ifẹ owo ni gbòngbo ohun buburu gbogbo: eyiti awọn miran nlepa ti a si mu wọn ṣako kuro ninu igbagbọ́, nwọn si fi ibinujẹ pupọ̀ gún ara wọn li ọ̀kọ̀.
Ṣàwárí I. Tim 6:10
3
I. Tim 6:6
Ṣugbọn iwa-bi-Ọlọrun pẹlu itẹlọrùn ère nla ni.
Ṣàwárí I. Tim 6:6
4
I. Tim 6:7
Nitori a kò mu ohun kan wá si aiye, bẹni a kò si le mu ohunkohun jade lọ.
Ṣàwárí I. Tim 6:7
5
I. Tim 6:17
Kìlọ fun awọn ti o lọrọ̀ li aiye isisiyi, ki nwọn máṣe gberaga, bẹni ki nwọn máṣe gbẹkẹle ọrọ̀ aidaniloju, bikoṣe le Ọlọrun alãye, ti nfi ohun gbogbo fun wa lọpọlọpọ lati lo
Ṣàwárí I. Tim 6:17
6
I. Tim 6:9
Ṣugbọn awọn ti nfẹ di ọlọrọ̀ a mã bọ́ sinu idanwò ati idẹkun, ati sinu wère ifẹkufẹ pipọ ti ipa-ni-lara, iru eyiti imã rì enia sinu iparun ati ègbé.
Ṣàwárí I. Tim 6:9
7
I. Tim 6:18-19
Ki nwọn ki o mã ṣõre, ki nwọn ki o mã pọ̀ ni iṣẹ rere, ki nwọn mura lati pin funni, ki nwọn ki o ni ẹmi ibakẹdun; Ki nwọn ki o mã tò iṣura ipilẹ rere jọ fun ara wọn dè igba ti mbọ̀, ki nwọn ki o le di ìye tõtọ mu.
Ṣàwárí I. Tim 6:18-19
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò