1
II. Kor 10:5
Bibeli Mimọ
Awa nsọ gbogbo ero kalẹ, ati gbogbo ohun giga ti ngbé ara rẹ̀ ga si ìmọ Ọlọrun, awa si ndi gbogbo ero ni igbekun wá si itẹriba fun Kristi
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí II. Kor 10:5
2
II. Kor 10:4
(Nitori ohun ija wa kì iṣe ti ara, ṣugbọn o li agbara ninu Ọlọrun lati wó ibi giga palẹ;)
Ṣàwárí II. Kor 10:4
3
II. Kor 10:3
Nitoripe bi awa tilẹ nrìn ni ti ara, ṣugbọn awa kò jagun nipa ti ara
Ṣàwárí II. Kor 10:3
4
II. Kor 10:18
Nitoripe kì iṣe ẹniti nyìn ara rẹ̀ li o yanju, bikoṣe ẹniti Oluwa yìn.
Ṣàwárí II. Kor 10:18
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò