1
II. Tes 3:3
Bibeli Mimọ
Ṣugbọn olododo li Oluwa, ẹniti yio fi ẹsẹ nyin mulẹ, ti yio si pa nyin mọ́ kuro ninu ibi.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí II. Tes 3:3
2
II. Tes 3:5
Ki Oluwa ki o si mã tọ́ ọkan nyin sinu ifẹ Ọlọrun, ati sinu sũru Kristi.
Ṣàwárí II. Tes 3:5
3
II. Tes 3:6
Awa si paṣẹ fun nyin, ará, li orukọ Jesu Kristi Oluwa wa, ki ẹnyin ki o yẹra kuro lọdọ olukuluku arakunrin, ti nrin ségesège, ti kì iṣe gẹgẹ bi ìlana ti nwọn ti gbà lọwọ wa.
Ṣàwárí II. Tes 3:6
4
II. Tes 3:2
Ati ki a le gbà wa lọwọ awọn aṣodi ati awọn enia buburu: nitoripe ki iṣe gbogbo enia li o gbagbọ́.
Ṣàwárí II. Tes 3:2
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò