1
Iṣe Apo 17:27
Bibeli Mimọ
Ki nwọn ki o le mã wá Oluwa, boya bi ọkàn wọn ba le fà si i, ti wọn si ri i, bi o tilẹ ṣe pe kò jina si olukuluku wa
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Iṣe Apo 17:27
2
Iṣe Apo 17:26
O si ti fi ẹ̀jẹ kanna da gbogbo orilẹ-ede lati tẹ̀do si oju agbaiye, o si ti pinnu akokò ti a yàn tẹlẹ, ati àla ibugbe wọn
Ṣàwárí Iṣe Apo 17:26
3
Iṣe Apo 17:24
Ọlọrun na ti o da aiye ati ohun gbogbo ti mbẹ ninu rẹ̀, on na ti iṣe Oluwa ọrun on aiye, kì igbé ile ti a fi ọwọ́ kọ́
Ṣàwárí Iṣe Apo 17:24
4
Iṣe Apo 17:31
Niwọnbi o ti da ọjọ kan, ninu eyi ti yio ṣe idajọ aiye li ododo, nipasẹ ọkunrin na ti o ti yàn, nigbati o ti fi ohun idaniloju fun gbogbo enia, niti o jí i dide kuro ninu okú.
Ṣàwárí Iṣe Apo 17:31
5
Iṣe Apo 17:29
Njẹ bi awa ba ṣe ọmọ Ọlọrun, kò yẹ fun wa ki a rò pe, Iwa-Ọlọrun dabi wura, tabi fadaka, tabi okuta, ti a fi ọgbọ́n ati ihumọ enia ṣe li ọnà.
Ṣàwárí Iṣe Apo 17:29
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò