1
O. Daf 85:2
Bibeli Mimọ
Iwọ ti dari aiṣedede awọn enia rẹ jì, iwọ ti bò gbogbo ẹ̀ṣẹ wọn mọlẹ.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí O. Daf 85:2
2
O. Daf 85:10
Ãnu ati otitọ padera; ododo ati alafia ti fi ẹnu kò ara wọn li ẹnu.
Ṣàwárí O. Daf 85:10
3
O. Daf 85:9
Nitõtọ igbala rẹ̀ sunmọ́ awọn ti o bẹ̀ru rẹ̀; ki ogo ki o le ma gbé ilẹ wa.
Ṣàwárí O. Daf 85:9
4
O. Daf 85:13
Ododo yio ṣãju rẹ̀; yio si fi ipasẹ rẹ̀ ṣe ọ̀na.
Ṣàwárí O. Daf 85:13
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò