1
2 Tẹsalonika 3:3
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Ṣùgbọ́n olódodo ni Olúwa, ẹni tí yóò fi ẹsẹ̀ yín múlẹ̀, tí yóò sì pa yín mọ́ kúrò nínú ibi.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí 2 Tẹsalonika 3:3
2
2 Tẹsalonika 3:5
Kí Olúwa máa tọ́ ọkàn yín ṣọ́nà sí ìfẹ́ Ọlọ́run àti sínú sùúrù Kristi.
Ṣàwárí 2 Tẹsalonika 3:5
3
2 Tẹsalonika 3:6
Ní orúkọ Jesu Kristi Olúwa wa, àwa pàṣẹ fún un yín ará, pé kí ẹ yẹra fún gbogbo àwọn arákùnrin yín tí ń ṣe ìmẹ́lẹ́, tí kò sì gbé ní ìbámu pẹ̀lú ẹ̀kọ́ tí ẹ gbà ní ọ̀dọ̀ wa.
Ṣàwárí 2 Tẹsalonika 3:6
4
2 Tẹsalonika 3:2
Kí ẹ sì máa gbàdúrà fún wa kí a lè bọ́ lọ́wọ́ àwọn ìkà àti àwọn ènìyàn búburú, nítorí pé kì í ṣe gbogbo ènìyàn ló ní ìgbàgbọ́.
Ṣàwárí 2 Tẹsalonika 3:2
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò