1
Ìṣe àwọn Aposteli 15:11
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Ṣùgbọ́n àwa gbàgbọ́ pé nípa oore-ọ̀fẹ́ Olúwa Jesu àwa ó là, gẹ́gẹ́ bí àwọn.”
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Ìṣe àwọn Aposteli 15:11
2
Ìṣe àwọn Aposteli 15:8-9
Ọlọ́run, tí ó jẹ́ olùmọ̀-ọkàn, sì jẹ́ wọn lẹ́rìí, ó fún wọn ni Ẹ̀mí Mímọ́, gẹ́gẹ́ bí àwa. Kò sí fi ìyàtọ̀ sí àárín àwa àti àwọn, ó ń fi ìgbàgbọ́ wẹ̀ wọ́n lọ́kàn mọ́.
Ṣàwárí Ìṣe àwọn Aposteli 15:8-9
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò