1
Ìṣe àwọn Aposteli 17:27
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Ọlọ́run ṣe eléyìí kí wọn bá le máa wa, bóyá wọn yóò lè ṣàfẹ́rí rẹ̀, kí wọn sì rí í. Bí ó tilẹ̀ jẹ pé kò jìnnà sí olúkúlùkù wa
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Ìṣe àwọn Aposteli 17:27
2
Ìṣe àwọn Aposteli 17:26
Ó sì tí tipasẹ̀ ẹnìkan dá gbogbo orílẹ̀-èdè láti tẹ̀dó sí ojú àgbáyé, ó sì ti pinnu àkókò tí a yàn tẹ́lẹ̀, àti ààlà ibùgbé wọn
Ṣàwárí Ìṣe àwọn Aposteli 17:26
3
Ìṣe àwọn Aposteli 17:24
“Ọlọ́run náà tí ó dá ayé àti ohun gbogbo tí ń bẹ nínú rẹ̀, òun náà tí í ṣe Olúwa ọ̀run àti ayé, kì í gbé tẹmpili tí a fi ọwọ́ kọ́
Ṣàwárí Ìṣe àwọn Aposteli 17:24
4
Ìṣe àwọn Aposteli 17:31
Níwọ́n bí ó ti dá ọjọ́ kan, nínú èyí tí yóò ṣe ìdájọ́ ayé lódodo nípasẹ̀ ọkùnrin náà tí ó ti yàn, nígbà tí ó ti fi ohun ìdánilójú fún gbogbo ènìyàn, ní ti pé ó jí dìde kúrò nínú òkú.”
Ṣàwárí Ìṣe àwọn Aposteli 17:31
5
Ìṣe àwọn Aposteli 17:29
“Ǹjẹ́ bí àwa bá jẹ́ ọmọ Ọlọ́run, kò yẹ fún wa láti rò pé, ẹni tí a wa n sìn dàbí wúrà, tàbí fàdákà, tàbí òkúta, tí a fi ọgbọ́n àti ìmọ̀ ènìyàn ya ère àwòrán rẹ̀.
Ṣàwárí Ìṣe àwọn Aposteli 17:29
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò