1
Saamu 86:11
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Kọ́ mi ní ọ̀nà rẹ, OLúWA, èmi ó sì máa rìn nínú òtítọ́ rẹ; fún mi ní ọkàn tí kì í yapa, kí èmi kí ó ba lè bẹ̀rù orúkọ rẹ.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Saamu 86:11
2
Saamu 86:5
Ìwọ ń dáríjì, ìwọ sì dára, OLúWA, ìwọ sì ṣàánú fún gbogbo àwọn tí ń ké pè ọ́
Ṣàwárí Saamu 86:5
3
Saamu 86:15
Ṣùgbọ́n ìwọ, OLúWA, jẹ́ aláàánú àti Ọlọ́run olójúrere, Ó lọ́ra láti bínú, Ó sì pọ̀ ní ìfẹ́ àti òtítọ́.
Ṣàwárí Saamu 86:15
4
Saamu 86:12
Èmi ó yìn ọ́, Olúwa Ọlọ́run mi, pẹ̀lú gbogbo ọkàn mi; èmi ó fògo fún orúkọ rẹ títí láé
Ṣàwárí Saamu 86:12
5
Saamu 86:7
Ní ọjọ́ ìpọ́njú mi èmi yóò pè ọ́, nítorí ìwọ yóò dá mi lóhùn.
Ṣàwárí Saamu 86:7
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò