1
Sekariah 4:6
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Ó sì dáhùn ó sì wí fún mi pé, “Èyí ni ọ̀rọ̀ OLúWA sí Serubbabeli tó wí pé: ‘Kì í ṣe nípa ipá, kì í ṣe nípa agbára, bí kò ṣe nípa Ẹ̀mí mi,’ ni OLúWA àwọn ọmọ-ogun wí.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Sekariah 4:6
2
Sekariah 4:10
“Ṣùgbọ́n ta ni ha kẹ́gàn ọjọ́ ohun kékeré? Nítorí wọn ó yọ̀ nígbà ti wọ́n bá rí okùn ìwọ̀n nì lọ́wọ́ Serubbabeli. “(Àwọn méje wọ̀nyí ni àwọn ojú OLúWA, tí ó ń sáré síhìn-ín sọ́hùn-ún ní gbogbo ayé.)”
Ṣàwárí Sekariah 4:10
3
Sekariah 4:9
“Ọwọ́ Serubbabeli ni a ti ṣe ìpìlẹ̀ ilé yìí, ọwọ́ rẹ̀ ni yóò sì parí rẹ̀; ìwọ yóò sì mọ̀ pé, OLúWA àwọn ọmọ-ogun ni ó rán mi sí i yín.
Ṣàwárí Sekariah 4:9
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò