TẸSALONIKA KEJI 3:3

TẸSALONIKA KEJI 3:3 YCE

Ṣugbọn olódodo ni Oluwa, òun ni yóo fi ẹsẹ̀ yín múlẹ̀, tí yóo sì pa yín mọ́ kúrò ninu ibi gbogbo.