ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 11:2

ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 11:2 YCE

Gbin àwọn kan síhìn-ín, gbin àwọn kan sọ́hùn-ún, gbìn ín káàkiri oko nítorí o kò mọ ohun tí ó lè ṣẹlẹ̀ lẹ́yìn ọ̀la.