ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 11:5

ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 11:5 YCE

Gẹ́gẹ́ bí o kò ti mọ bí ẹ̀mí ṣe ń wọ inú ọmọ ninu aboyún, bẹ́ẹ̀ ni o kò mọ̀ bí Ọlọrun ṣe dá ohun gbogbo.