ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 11:6

ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 11:6 YCE

Fún irúgbìn ní àárọ̀, má sì ṣe dáwọ́ dúró ní ìrọ̀lẹ́, nítorí o kò mọ èyí tí yóo dàgbà, bóyá ti òwúrọ̀ ni tabi ti ìrọ̀lẹ́, tabi àwọn mejeeji.