ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 4:12

ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 4:12 YCE

Ẹyọ ẹnìkan ṣoṣo ni eniyan kan lè dojú ìjà kọ, nítorí pé eniyan meji lè gba ara wọn kalẹ̀. Okùn onípọn mẹta kò lè ṣe é já bọ̀rọ̀.