ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 4:13

ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 4:13 YCE

Ọlọ́gbọ́n ọdọmọde tí ó jẹ́ talaka, sàn ju òmùgọ̀ àgbàlagbà ọba, tí kò jẹ́ gba ìmọ̀ràn lọ