ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 8:14

ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 8:14 YCE

Ohun asán kan tún wà tí ń ṣẹlẹ̀ nílé ayé yìí, a rí àwọn olódodo tí wọn ń jẹ ìyà àwọn eniyan burúkú, tí eniyan burúkú sì ń gba èrè olódodo, asán ni èyí pẹlu.