ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 9:5

ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 9:5 YCE

Nítorí alààyè mọ̀ pé òun óo kú, ṣugbọn òkú kò mọ nǹkankan mọ́, bẹ́ẹ̀ ni wọn kò ní èrè kan mọ́, a kò sì ní ranti wọn mọ́.