Joṣua 2:11

Joṣua 2:11 YCB

Bí a ti gbọ́ nǹkan wọ̀nyí, ọkàn wa pami kò sì sí okun kankan fún wa mọ́ nítorí i yín, nítorí pé OLúWA Ọlọ́run yín ni Ọlọ́run ní òkè ọ̀run àti ní ayé.