I. Joh 4:4
I. Joh 4:4 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ẹnyin ọmọ mi, ti Ọlọrun li ẹnyin, ẹnyin si ti ṣẹgun wọn: nitori ẹniti mbẹ ninu nyin tobi jù ẹniti mbẹ ninu aiye lọ.
Pín
Kà I. Joh 4I. Joh 4:4 Yoruba Bible (YCE)
Ẹ̀yin ọmọde, ti Ọlọrun nìyí, ẹ ti ṣẹgun ẹ̀mí alátakò Kristi nítorí pé ẹni tí ó wà ninu yín tóbi ju ẹni tí ó wà ninu ayé lọ.
Pín
Kà I. Joh 4