II. Tes 3:3
II. Tes 3:3 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ṣugbọn olododo li Oluwa, ẹniti yio fi ẹsẹ nyin mulẹ, ti yio si pa nyin mọ́ kuro ninu ibi.
Pín
Kà II. Tes 3II. Tes 3:3 Yoruba Bible (YCE)
Ṣugbọn olódodo ni Oluwa, òun ni yóo fi ẹsẹ̀ yín múlẹ̀, tí yóo sì pa yín mọ́ kúrò ninu ibi gbogbo.
Pín
Kà II. Tes 3