Efe 1:7
Efe 1:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)
Nínú rẹ̀ ni àwa rí ìràpadà gba nípa ẹ̀jẹ̀ rẹ̀ àti ìdáríjì àwọn ẹ̀ṣẹ̀ wa, ní ìbámu pẹ̀lú ọrọ̀ oore-ọ̀fẹ́ Ọlọ́run
Pín
Kà Efe 1Efe 1:7 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ninu ẹniti awa ni irapada wa nipa ẹjẹ rẹ̀, idariji ẹ̀ṣẹ wa, gẹgẹ bi ọrọ̀ ore-ọfẹ rẹ̀
Pín
Kà Efe 1