1
ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 12:5
Yoruba Bible
YCE
Wọ́n bá sọ Peteru sẹ́wọ̀n, ṣugbọn gbogbo ìjọ ń fi tọkàntọkàn gbadura sí Ọlọrun nítorí rẹ̀.
Compare
Explore ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 12:5
2
ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 12:7
Angẹli Oluwa kan bá yọ dé, ìmọ́lẹ̀ sì tàn ninu ilé náà. Angẹli náà bá rọra lu Peteru lẹ́gbẹ̀ẹ́, ó jí i, ó ní, “Dìde kíá.” Àwọn ẹ̀wọ̀n tí wọ́n fi de Peteru bá yọ bọ́ kúrò ní ọwọ́ rẹ̀
Explore ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 12:7
Home
Bible
Plans
Videos