1
ẸKISODU 14:14
Yoruba Bible
OLUWA yóo jà fún yín, ẹ̀yin ẹ ṣá dúró jẹ́.”
Compare
Explore ẸKISODU 14:14
2
ẸKISODU 14:13
Mose bá dá àwọn eniyan náà lóhùn, ó ní, “Ẹ má bẹ̀rù, ẹ dúró gbọningbọnin, kí ẹ wá máa wo ohun tí OLUWA yóo ṣe. Ẹ óo rí i bí yóo ṣe gbà yín là lónìí; nítorí pé àwọn ará Ijipti tí ẹ̀ ń wò yìí, ẹ kò tún ní rí wọn mọ́ laelae.
Explore ẸKISODU 14:13
3
ẸKISODU 14:16
Gbé ọ̀pá rẹ sókè kí o na ọwọ́ sórí Òkun Pupa, kí ó sì pín in sí meji, kí àwọn eniyan Israẹli lè kọjá láàrin rẹ̀ lórí ìyàngbẹ ilẹ̀.
Explore ẸKISODU 14:16
4
ẸKISODU 14:31
Àwọn ọmọ Israẹli rí ohun ńlá tí OLUWA ṣe sí àwọn ará Ijipti, wọ́n bẹ̀rù OLUWA, wọ́n sì gba OLUWA gbọ́, ati Mose, iranṣẹ rẹ̀.
Explore ẸKISODU 14:31
Home
Bible
Plans
Videos