1
ORIN DAFIDI 141:3
Yoruba Bible
OLUWA, fi ìjánu sí mi ní ẹnu, sì ṣe aṣọ́nà ètè mi.
Compare
Explore ORIN DAFIDI 141:3
2
ORIN DAFIDI 141:4
Má jẹ́ kí ọkàn mi fà sí ibi, má sì jẹ́ kí n lọ́wọ́ sí iṣẹ́ ìkà. Má jẹ́ kí n bá àwọn oníṣẹ́ ẹ̀ṣẹ̀ rìn pọ̀, má sì jẹ́ kí n jẹ ninu oúnjẹ àdídùn wọn.
Explore ORIN DAFIDI 141:4
3
ORIN DAFIDI 141:1-2
OLUWA, mo ké pè ọ́, tètè wá dá mi lóhùn, tẹ́tí sí ohùn mi nígbà tí mo bá ń ké pè ọ́. Jẹ́ kí adura mi wá sí ọ̀dọ̀ rẹ bíi turari, sì jẹ́ kí ọwọ́ adura tí mo gbé sókè dàbí ẹbọ àṣáálẹ́.
Explore ORIN DAFIDI 141:1-2
Home
Bible
Plans
Videos