1
ORIN DAFIDI 142:5
Yoruba Bible
Mo ké pè ọ́, OLUWA, mo ní, “Ìwọ ni ààbò mi, ìwọ ni ìpín mi lórí ilẹ̀ alààyè.”
Compare
Explore ORIN DAFIDI 142:5
2
ORIN DAFIDI 142:7
Yọ mí kúrò ninu ìhámọ́, kí n lè yin orúkọ rẹ lógo. Àwọn olódodo yóo yí mi ká, nítorí ọpọlọpọ oore tí o óo ṣe fún mi.
Explore ORIN DAFIDI 142:7
3
ORIN DAFIDI 142:3
Nígbà tí ọkàn mi rẹ̀wẹ̀sì, ó mọ ọ̀nà tí mo lè gbà. Wọ́n ti dẹ tàkúté sílẹ̀ fún mi ní ọ̀nà tí mò ń rìn.
Explore ORIN DAFIDI 142:3
4
ORIN DAFIDI 142:1
Mo ké pe OLUWA, mo gbé ohùn ẹ̀bẹ̀ sókè sí i.
Explore ORIN DAFIDI 142:1
5
ORIN DAFIDI 142:6
Gbọ́ igbe mi; nítorí wọ́n ti rẹ̀ mí sílẹ̀ patapata. Gbà mí lọ́wọ́ àwọn tí ń ṣe inúnibíni mi, nítorí pé wọ́n lágbára jù mí lọ.
Explore ORIN DAFIDI 142:6
Home
Bible
Plans
Videos