1
ORIN DAFIDI 144:1
Yoruba Bible
Ìyìn ni fún OLUWA, àpáta mi, ẹni tí ó kọ́ mi ní ìjà jíjà, tí ó kọ́ mi ní iṣẹ́ ogun.
Compare
Explore ORIN DAFIDI 144:1
2
ORIN DAFIDI 144:15
Ayọ̀ ń bẹ fún orílẹ̀-èdè tí ó ní irú ibukun yìí; ayọ̀ ń bẹ fún orílẹ̀-èdè tí OLUWA jẹ́ Ọlọrun wọn.
Explore ORIN DAFIDI 144:15
3
ORIN DAFIDI 144:2
Òun ni àpáta mi, ààbò mi, odi mi, olùdáǹdè mi, asà mi, ẹni tí mo sá di. Òun ni ó tẹrí àwọn eniyan ba lábẹ́ rẹ̀.
Explore ORIN DAFIDI 144:2
4
ORIN DAFIDI 144:3
OLUWA, kí ni eniyan jẹ́, tí o fi ń náání rẹ̀? Kí sì ni ọmọ eniyan tí o fi ń ranti rẹ̀?
Explore ORIN DAFIDI 144:3
Home
Bible
Plans
Videos