1
ORIN DAFIDI 145:18
Yoruba Bible
OLUWA súnmọ́ gbogbo àwọn tí ń pè é, àní, àwọn tí ń pè é tọkàntọkàn.
Compare
Explore ORIN DAFIDI 145:18
2
ORIN DAFIDI 145:8
Aláàánú ni OLUWA, olóore sì ni; kì í yára bínú, ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ sì pọ̀.
Explore ORIN DAFIDI 145:8
3
ORIN DAFIDI 145:9
OLUWA ṣeun fún gbogbo eniyan, àánú rẹ̀ sì ń bẹ lórí gbogbo ohun tí ó dá.
Explore ORIN DAFIDI 145:9
4
ORIN DAFIDI 145:3
OLUWA tóbi, ìyìn sì yẹ ẹ́ lọpọlọpọ; àwámárìídìí ni títóbi rẹ̀.
Explore ORIN DAFIDI 145:3
5
ORIN DAFIDI 145:13
Ìjọba ayérayé ni ìjọba rẹ, yóo sì máa wà láti ìran dé ìran. Olóòótọ́ ni OLUWA ninu gbogbo ọ̀rọ̀ rẹ̀, olóore ọ̀fẹ́ sì ni ninu gbogbo ìṣe rẹ̀.
Explore ORIN DAFIDI 145:13
Home
Bible
Plans
Videos