1
ORIN DAFIDI 146:5
Yoruba Bible
Ayọ̀ ń bẹ fún ẹni tí ó fi Ọlọrun Jakọbu ṣe olùrànlọ́wọ́ rẹ̀, tí ó gbójú lé OLUWA, Ọlọrun rẹ̀.
Compare
Explore ORIN DAFIDI 146:5
2
ORIN DAFIDI 146:3
Má gbẹ́kẹ̀lé àwọn ìjòyè; eniyan ni wọ́n, kò sì sí ìgbàlà lọ́dọ̀ wọn.
Explore ORIN DAFIDI 146:3
3
ORIN DAFIDI 146:7-8
ẹni tíí máa ń dá ẹjọ́ òdodo fún àwọn tí a ni lára; tí ń fún àwọn tí ebi ń pa ní oúnjẹ, OLUWA tíí tú àwọn tí ó wà ninu ìdè sílẹ̀. A máa la ojú àwọn afọ́jú, a máa gbé àwọn tí a tẹrí wọn ba dúró; ó fẹ́ràn àwọn olódodo.
Explore ORIN DAFIDI 146:7-8
4
ORIN DAFIDI 146:6
Ọlọrun tí ó dá ọ̀run ati ayé, òkun ati gbogbo ohun tí ó wà ninu rẹ̀; Ọlọrun tíí máa ń pa àdéhùn rẹ̀ mọ́ títí lae
Explore ORIN DAFIDI 146:6
5
ORIN DAFIDI 146:9
OLUWA ni olùṣọ́ àwọn àlejò, òun ni alátìlẹ́yìn àwọn opó ati aláìníbaba, ṣugbọn a máa da ète àwọn eniyan burúkú rú.
Explore ORIN DAFIDI 146:9
Home
Bible
Plans
Videos