1
ORIN DAFIDI 147:3
Yoruba Bible
Ó ń tu àwọn tí ọkàn wọn bàjẹ́ ninu, ó sì ń dí ọgbẹ́ wọn.
Compare
Explore ORIN DAFIDI 147:3
2
ORIN DAFIDI 147:11
Ṣugbọn inú OLUWA dùn sí àwọn tí ó bẹ̀rù rẹ̀, àwọn tí ó ní ìrètí ninu ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀.
Explore ORIN DAFIDI 147:11
3
ORIN DAFIDI 147:5
OLUWA wa tóbi, ó sì lágbára pupọ òye rẹ̀ kò ní ìwọ̀n.
Explore ORIN DAFIDI 147:5
4
ORIN DAFIDI 147:4
Òun ló mọ iye àwọn ìràwọ̀, òun ló sì fún gbogbo wọn lórúkọ.
Explore ORIN DAFIDI 147:4
5
ORIN DAFIDI 147:6
OLUWA ní ń gbé àwọn onírẹ̀lẹ̀ ró, òun ni ó sì ń sọ àwọn eniyan burúkú di ilẹ̀ẹ́lẹ̀.
Explore ORIN DAFIDI 147:6
Home
Bible
Plans
Videos