1
ORIN DAFIDI 18:2
Yoruba Bible
OLUWA ni àpáta mi, ibi ààbò mi, ati olùgbàlà mi; Ọlọrun mi, àpáta mi, ninu ẹni tí ààbò mi wà. Òun ni asà mi, ìwo ìgbàlà mi ati ibi ìsásí mi.
Compare
Explore ORIN DAFIDI 18:2
2
ORIN DAFIDI 18:30
Ní ti Ọlọrun, ọ̀nà rẹ̀ pé, pípé ni ọ̀rọ̀ OLUWA; òun sì ni ààbò fún gbogbo àwọn tí ó sá di í.
Explore ORIN DAFIDI 18:30
3
ORIN DAFIDI 18:3
Mo ké pe OLUWA, ẹni tí ìyìn yẹ, ó sì gbà mí lọ́wọ́ àwọn ọ̀tá mi.
Explore ORIN DAFIDI 18:3
4
ORIN DAFIDI 18:6
Ninu ìpọ́njú mi mo ké pe OLUWA, Ọlọrun mi ni mo ké pè. Ó gbọ́ ohùn mi láti inú ilé mímọ́ rẹ̀, ó sì tẹ́tí sí igbe mi.
Explore ORIN DAFIDI 18:6
5
ORIN DAFIDI 18:28
Nítorí ìwọ ni o mú kí àtùpà mi máa tàn, OLUWA, Ọlọrun mi ni ó tan ìmọ́lẹ̀ sí òkùnkùn mi.
Explore ORIN DAFIDI 18:28
6
ORIN DAFIDI 18:32
Ọlọrun tí ó gbé agbára wọ̀ mí, tí ó sì mú ọ̀nà mi pé.
Explore ORIN DAFIDI 18:32
7
ORIN DAFIDI 18:46
OLUWA wà láàyè! Ẹni ìyìn ni àpáta mi! Ẹni àgbéga ni Ọlọrun ìgbàlà mi!
Explore ORIN DAFIDI 18:46
Home
Bible
Plans
Videos